Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
![](https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/4/46/Wbar_blue.jpg) Àyọkà pàtàkì ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀ Adeniran Ogunsanya, amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Adeniran Ogunsanya QC, SAN (31 January 1918 – 22 November 1996) jẹ́ amòfin àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó sì tún jẹ́ ọ̀kan pàtàkì lára àwọn olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú Ibadan Peoples Party (IPP). Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí Kọmíṣọ́nà fún ètò ìdájọ́ ati ètò ẹ̀kọ́ fún Ìpínlẹ̀ Èkó ní àsìkò ìṣèjọba alágbádá ẹlẹ́kejì. Òun náà tún ni alága pátá pátá fún ẹgbẹ́ òṣèlú Nigerian People's Party nígbà ayé rẹ̀. Wọ́n bí Adéníran ní ọjọ́ Kọkànlélógún oṣù Kíní ọdún 1918 ní agbègbè Ìkòròdú ní Ìpínlẹ̀ Èkó sí agboolé ọmọ Ọba Sùbérù Ògúnsànyà Ògúntádé tí ó jẹ́ Ọdọ̀fin ti ìlú Ìkòròdú nígbà náà. Adéníran lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Hope Waddell Training Institute ní ìlú Calabar nígbà tí ó ń gbé pẹ̀lú àbúrò bàbá rẹ̀ tí ó jẹ́ òṣìṣẹ́ ìjọba ní ìlú Calaba. Ìjọba fi ẹ̀bùn ẹ̀kọ́-ọ̀fẹ́ dá Adéníra lọ̀lá láti kàwé síwájú si ní ilé-ẹ̀kọ́ King's College tí ó wà ní Ìpínlẹ̀ Èkó látàrí bí ó ṣe peregedé jùlọ pẹ̀lú máàkì tí ó ga jùlọ nínú ìdánwò àṣekágbá ti Standard VI (6) ní ọdún 1937. Ó tẹ̀ siwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀, tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ òfin ní ilé-ẹ̀kọ́ fásitì ti University of Manchester àti Gray's Inn tí ó jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ ìmọ̀ òfin.(ìtẹ̀síwájú...) ![](https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/9/90/Wbar_green2.jpg) Ní ọjọ́ òní... Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 11 Oṣù Èrèlé ![](https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/e/e9/Wbar_green3.jpg) Ṣé ẹ mọ̀ pé...? ... ni ile Yoruba, Oyo Mesi ni igbimo afobaje ati asofin ni Ilẹ̀ Ọ̀yọ́? ... that in physics, absolute zero is the temperature where the particles of matter stop moving? ... that the furthest away from the centre of the Earth one can get is at the top of Mount Chimborazo (pictured) in Ecuador, not the top of Mount Everest? ... that Barack Obama is the first black president of the United States of America? |
![](https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/7/71/Wbar_green1.jpg) Ìròyìn ìwòyí Àjàkáyé-àrùn COVID-19 SARS-CoV-2 Àrún COVID-19 COVID-19 ní Nàìjíríà Ìjàmbá ìtúká olóró ṣẹlẹ̀ ní Bèírùtù, Lẹ́bánọ́nù. Ó fikú pa àwọn ènìyàn tó tó 171. John Lewis ọmọ ọdún 80, alákitiyan àti olóṣèlú ará Amẹ́ríkà ṣe aláìsí ní ìlú Atlanta, USA. Ààrẹ ilẹ̀ Bùrúndì, Pierre Nkurunziza (fọ́tò) ṣe aláìsí ní Bùrúndì. Bàálù agbérò ti Pakistan International Airlines jálulẹ̀ nítòsí Karachi, ó ṣe ikú pa àwọn ènìyàn àádôrun lé méje. Ẹ tún wo ÌròyìnWiki ní èdè Gẹ̀ẹ́sì ![](https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/e/e8/Wbar_pink.jpg) Àwòrán ọjọ́ òní Àwọn òrùlé pupa àwọn ilé ní Piran, Sloféníà. ![](https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/e/e8/Wbar_pink.jpg) Àwọn Iṣẹ́-ọwọ́ Míràn Wikimedia Foundation ni ó gba àlejò Wikipedia, egbe-alasepo ti ki se fun ere ti o tun se alejo opo awon ise-owo miran: WikiàyásọÀkójọ àwọn àmúsọ Wikiatúmọ̀èdèAtúmọ̀èdè orísirísi èdè WikispeciesÀkójọ àwọn irú ẹ̀dá **Wikinews**Ìròyìn ọ́fẹ̀ WikisourceÀwọn àkọsíìwé ọ̀fẹ́ Wikimedia CommonsÀwòrán, ìró àti fídéò WikifásítìÈlò ìkọ́ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ WikiìwéÌwéẹ̀kọ́ àti ìwéàwòṣe ọ̀fẹ́ **Meta-Wiki**Ibi àkóso ìṣẹ́-ọwọ́ Wikimedia WikidataÌbùdó ìmò ọ̀fẹ́ Àkíyèsí! — Àìṣojúṣájú · Ìlànà àyọkà kíkọ · Ẹ̀tọ́àwòkọ · Ìwà títọ́ · Ìṣeéyẹ̀wò · Ìlànà fún kíkọ lẹ́tà Yorùbá Kíkọ àyọkà — Kíni Wikipedia jẹ́? · Àtúnṣe ojúewé · Àfikún àwòrán · Ìkópa · Tutorial · Àpótí ìdánwò Ìrànwọ́ Wikipedia — Àwọn ojúewé tuntun · Àwọn àyọkà ọ̀wọ́n · Àwọn ojúewé fún ìyílédèdà · Àwọn àyọkà fún àtúnṣe · Ìṣọrẹ Nípa Wikipédia — Abẹ́ igi · FAQ · Àwọn oníṣe Wikipedia · Àwọn alámùójútó · Wikimedia · Software · Àwọn statístíkì Orúkọàyè — Wikipedia |
Wikipedia ní àwọn èdè míràn